-
Lúùkù 23:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ó tú ọkùnrin tí wọ́n fẹ́ sílẹ̀, ẹni tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n torí ìdìtẹ̀ sí ìjọba àti ìpànìyàn, àmọ́ ó fa Jésù lé wọn lọ́wọ́ kí wọ́n lè ṣe ohun tí wọ́n fẹ́ sí i.
-