-
Máàkù 15:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Wọ́n kọ ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án pé: “Ọba Àwọn Júù.”+
-
-
Lúùkù 23:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Àkọlé kan tún wà lórí rẹ̀ pé: “Ọba Àwọn Júù nìyí.”+
-