Máàkù 14:62 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 62 Jésù wá sọ pé: “Èmi ni; ẹ sì máa rí Ọmọ èèyàn+ tó jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún agbára,+ tó sì ń bọ̀ pẹ̀lú àwọsánmà* ojú ọ̀run.”+ Jòhánù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ìdí nìyí tí àwọn Júù fi túbọ̀ ń wá bí wọ́n ṣe máa pa á, torí kì í ṣe pé kò pa Sábáàtì mọ́ nìkan ni, àmọ́ ó tún ń pe Ọlọ́run ní Baba rẹ̀,+ ó ń sọ pé òun àti Ọlọ́run dọ́gba.+ Jòhánù 10:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 ṣé èmi tí Baba sọ di mímọ́, tó sì rán wá sí ayé lẹ wá ń sọ fún pé, ‘O sọ̀rọ̀ òdì,’ torí mo sọ pé, ‘Ọmọ Ọlọ́run ni mí’?+
62 Jésù wá sọ pé: “Èmi ni; ẹ sì máa rí Ọmọ èèyàn+ tó jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún agbára,+ tó sì ń bọ̀ pẹ̀lú àwọsánmà* ojú ọ̀run.”+
18 Ìdí nìyí tí àwọn Júù fi túbọ̀ ń wá bí wọ́n ṣe máa pa á, torí kì í ṣe pé kò pa Sábáàtì mọ́ nìkan ni, àmọ́ ó tún ń pe Ọlọ́run ní Baba rẹ̀,+ ó ń sọ pé òun àti Ọlọ́run dọ́gba.+
36 ṣé èmi tí Baba sọ di mímọ́, tó sì rán wá sí ayé lẹ wá ń sọ fún pé, ‘O sọ̀rọ̀ òdì,’ torí mo sọ pé, ‘Ọmọ Ọlọ́run ni mí’?+