Mátíù 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bí ẹ ṣe ń lọ, ẹ máa wàásù pé: ‘Ìjọba ọ̀run ti sún mọ́lé.’+ Máàkù 1:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn tí wọ́n mú Jòhánù, Jésù lọ sí Gálílì,+ ó ń wàásù ìhìn rere Ọlọ́run,+ 15 ó ń sọ pé: “Àkókò tí a yàn ti pé, Ìjọba Ọlọ́run sì ti sún mọ́lé. Ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú ìhìn rere.”
14 Lẹ́yìn tí wọ́n mú Jòhánù, Jésù lọ sí Gálílì,+ ó ń wàásù ìhìn rere Ọlọ́run,+ 15 ó ń sọ pé: “Àkókò tí a yàn ti pé, Ìjọba Ọlọ́run sì ti sún mọ́lé. Ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú ìhìn rere.”