-
Máàkù 16:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àmọ́ nígbà tí wọ́n gbójú sókè, wọ́n rí i pé a ti yí òkúta náà kúrò, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ó tóbi gan-an.+ 5 Nígbà tí wọ́n wọnú ibojì náà, wọ́n rí ọ̀dọ́kùnrin kan tó jókòó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀tún, ó wọ aṣọ funfun, ẹnu sì yà wọ́n.
-
-
Lúùkù 24:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Bí wọ́n ṣe ń ro ọ̀rọ̀ náà torí ó rú wọn lójú, wò ó! ọkùnrin méjì tí aṣọ wọn ń kọ mànà dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ wọn.
-