23 Ní ti èyí tó bọ́ sórí iyẹ̀pẹ̀ tó dáa, òun ló ń gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, tó sì ń yé e, tó so èso lóòótọ́, tó sì ń mú èso jáde, eléyìí so ní ìlọ́po ọgọ́rùn-ún (100), ìyẹn ọgọ́ta (60), òmíràn ọgbọ̀n (30).”+
15 Ní ti èyí tó wà lórí iyẹ̀pẹ̀ tó dáa, àwọn yìí ló jẹ́ pé, lẹ́yìn tí wọ́n fi ọkàn tó tọ́, tó sì dáa gbọ́ ọ̀rọ̀ náà,+ wọ́n fi sọ́kàn, wọ́n sì ń fi ìfaradà so èso.+