-
Òwe 1:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ọlọ́gbọ́n máa ń fetí sílẹ̀, á sì kọ́ ẹ̀kọ́ sí i;+
Olóye máa ń gba ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n+
-
Mátíù 11:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Kí ẹni tó bá ní etí fetí sílẹ̀.
-
-
-