Lúùkù 8:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Nígbà tí Jésù gbọ́ èyí, ó dá a lóhùn pé: “Má bẹ̀rù, ṣáà ti ní ìgbàgbọ́, ara ọmọ náà sì máa yá.”+ Jòhánù 11:39, 40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Jésù sọ pé: “Ẹ gbé òkúta náà kúrò.” Màtá, arábìnrin olóògbé náà, sọ fún un pé: “Olúwa, á ti máa rùn báyìí, torí ó ti pé ọjọ́ mẹ́rin.” 40 Jésù sọ fún un pé: “Ṣebí mo sọ fún ọ pé tí o bá gbà gbọ́, o máa rí ògo Ọlọ́run?”+
39 Jésù sọ pé: “Ẹ gbé òkúta náà kúrò.” Màtá, arábìnrin olóògbé náà, sọ fún un pé: “Olúwa, á ti máa rùn báyìí, torí ó ti pé ọjọ́ mẹ́rin.” 40 Jésù sọ fún un pé: “Ṣebí mo sọ fún ọ pé tí o bá gbà gbọ́, o máa rí ògo Ọlọ́run?”+