Lúùkù 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Lẹ́yìn àwọn nǹkan yìí, Olúwa yan àwọn àádọ́rin (70) míì, ó sì rán wọn jáde ṣáájú rẹ̀ ní méjì-méjì+ sínú gbogbo ìlú àti ibi tí òun fúnra rẹ̀ máa lọ.
10 Lẹ́yìn àwọn nǹkan yìí, Olúwa yan àwọn àádọ́rin (70) míì, ó sì rán wọn jáde ṣáájú rẹ̀ ní méjì-méjì+ sínú gbogbo ìlú àti ibi tí òun fúnra rẹ̀ máa lọ.