Lúùkù 3:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ torí pé Jòhánù ti bá Hẹ́rọ́dù alákòóso agbègbè náà wí nípa Hẹrodíà ìyàwó arákùnrin rẹ̀ àti nípa gbogbo ohun burúkú tí Hẹ́rọ́dù ṣe, 20 ó tún fi èyí kún gbogbo ohun tó ṣe yẹn: Ó ti Jòhánù mọ́nú ẹ̀wọ̀n.+
19 Àmọ́ torí pé Jòhánù ti bá Hẹ́rọ́dù alákòóso agbègbè náà wí nípa Hẹrodíà ìyàwó arákùnrin rẹ̀ àti nípa gbogbo ohun burúkú tí Hẹ́rọ́dù ṣe, 20 ó tún fi èyí kún gbogbo ohun tó ṣe yẹn: Ó ti Jòhánù mọ́nú ẹ̀wọ̀n.+