Mátíù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bó ṣe ń rìn lọ létí Òkun Gálílì, ó rí àwọn méjì tí wọ́n jẹ́ tẹ̀gbọ́n-tàbúrò, Símónì tí wọ́n ń pè ní Pétérù+ àti Áńdérù arákùnrin rẹ̀, tí wọ́n ń ju àwọ̀n sínú òkun, torí apẹja ni wọ́n.+
18 Bó ṣe ń rìn lọ létí Òkun Gálílì, ó rí àwọn méjì tí wọ́n jẹ́ tẹ̀gbọ́n-tàbúrò, Símónì tí wọ́n ń pè ní Pétérù+ àti Áńdérù arákùnrin rẹ̀, tí wọ́n ń ju àwọ̀n sínú òkun, torí apẹja ni wọ́n.+