ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 8:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ó sọ fún àwọn èrò náà pé kí wọ́n jókòó sílẹ̀.* Ó wá mú búrẹ́dì méje náà, ó dúpẹ́, ó bù ú, ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé kí wọ́n pín in, wọ́n sì pín in fún àwọn èrò náà.+

  • Lúùkù 24:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Bó ṣe ń bá wọn jẹun,* ó mú búrẹ́dì, ó súre sí i, ó bù ú, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í fún wọn.+

  • Ìṣe 27:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Lẹ́yìn tó sọ ọ̀rọ̀ yìí, ó mú búrẹ́dì, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run níwájú gbogbo wọn, ó bù ú, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í jẹun.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́