Mátíù 15:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Jésù kúrò níbẹ̀, ó wá lọ sí tòsí Òkun Gálílì,+ ó lọ sórí òkè, ó sì jókòó síbẹ̀.