Mátíù 7:28, 29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbà tí Jésù sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí tán, ohun tó ṣẹlẹ̀ ni pé bó ṣe ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ ya àwọn èrò náà lẹ́nu,+ 29 torí ṣe ló ń kọ́ wọn bí ẹni tó ní àṣẹ,+ kò kọ́ wọn bí àwọn akọ̀wé òfin wọn.
28 Nígbà tí Jésù sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí tán, ohun tó ṣẹlẹ̀ ni pé bó ṣe ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ ya àwọn èrò náà lẹ́nu,+ 29 torí ṣe ló ń kọ́ wọn bí ẹni tó ní àṣẹ,+ kò kọ́ wọn bí àwọn akọ̀wé òfin wọn.