Lúùkù 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn àpọ́sítélì wá sọ fún Olúwa pé: “Fún wa ní ìgbàgbọ́ sí i.”+