Mátíù 25:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Ọba máa dá wọn lóhùn pé, ‘Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, torí pé ẹ ti ṣe é fún ọ̀kan lára àwọn arákùnrin mi tó kéré jù lọ yìí, ẹ ti ṣe é fún mi.’+
40 Ọba máa dá wọn lóhùn pé, ‘Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, torí pé ẹ ti ṣe é fún ọ̀kan lára àwọn arákùnrin mi tó kéré jù lọ yìí, ẹ ti ṣe é fún mi.’+