Diutarónómì 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Tí ọkùnrin kan bá fẹ́ obìnrin kan, àmọ́ tí obìnrin náà ò tẹ́ ẹ lọ́rùn torí ó rí ohun kan tí kò dáa nípa rẹ̀, kó kọ ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀ fún un,+ kó fi lé e lọ́wọ́, kó sì ní kó kúrò ní ilé òun.+ Mátíù 5:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “A tún sọ pé: ‘Ẹnikẹ́ni tó bá kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, kó fún un ní ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀.’+ Mátíù 19:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n sọ fún un pé: “Kí ló wá dé tí Mósè fi sọ pé ká fún un ní ìwé ẹ̀rí láti lé e lọ, ká sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀?”+
24 “Tí ọkùnrin kan bá fẹ́ obìnrin kan, àmọ́ tí obìnrin náà ò tẹ́ ẹ lọ́rùn torí ó rí ohun kan tí kò dáa nípa rẹ̀, kó kọ ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀ fún un,+ kó fi lé e lọ́wọ́, kó sì ní kó kúrò ní ilé òun.+
7 Wọ́n sọ fún un pé: “Kí ló wá dé tí Mósè fi sọ pé ká fún un ní ìwé ẹ̀rí láti lé e lọ, ká sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀?”+