Mátíù 3:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn èèyàn Jerúsálẹ́mù àti gbogbo Jùdíà àti gbogbo ìgbèríko tó yí Jọ́dánì ká máa ń lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ 6 ó ń ṣèrìbọmi* fún wọn ní odò Jọ́dánì,+ wọ́n sì ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn ní gbangba.
5 Àwọn èèyàn Jerúsálẹ́mù àti gbogbo Jùdíà àti gbogbo ìgbèríko tó yí Jọ́dánì ká máa ń lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ 6 ó ń ṣèrìbọmi* fún wọn ní odò Jọ́dánì,+ wọ́n sì ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn ní gbangba.