Jóòbù 42:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Mo ti wá mọ̀ pé o lè ṣe ohun gbogboÀti pé kò sí ohun tó wà lọ́kàn rẹ tí kò ní ṣeé ṣe fún ọ.+