Mátíù 9:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Bí Jésù ṣe kúrò níbẹ̀, àwọn ọkùnrin afọ́jú méjì + tẹ̀ lé e, wọ́n ń kígbe pé: “Ṣàánú wa, Ọmọ Dáfídì.” Mátíù 15:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Wò ó! obìnrin ará Foníṣíà kan láti agbègbè yẹn wá, ó sì ń ké jáde pé: “Ṣàánú mi, Olúwa, Ọmọ Dáfídì. Ẹ̀mí èṣù ń yọ ọmọbìnrin mi lẹ́nu gidigidi.”+
27 Bí Jésù ṣe kúrò níbẹ̀, àwọn ọkùnrin afọ́jú méjì + tẹ̀ lé e, wọ́n ń kígbe pé: “Ṣàánú wa, Ọmọ Dáfídì.”
22 Wò ó! obìnrin ará Foníṣíà kan láti agbègbè yẹn wá, ó sì ń ké jáde pé: “Ṣàánú mi, Olúwa, Ọmọ Dáfídì. Ẹ̀mí èṣù ń yọ ọmọbìnrin mi lẹ́nu gidigidi.”+