Mátíù 21:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà tí àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin rí àwọn ohun ìyanu tó ṣe àti àwọn ọmọkùnrin tó ń kígbe nínú tẹ́ńpìlì pé, “A bẹ̀ ọ́, gba Ọmọ Dáfídì là!”+ inú bí wọn gidigidi,+
15 Nígbà tí àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin rí àwọn ohun ìyanu tó ṣe àti àwọn ọmọkùnrin tó ń kígbe nínú tẹ́ńpìlì pé, “A bẹ̀ ọ́, gba Ọmọ Dáfídì là!”+ inú bí wọn gidigidi,+