Máàkù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jòhánù Onírìbọmi wà nínú aginjù, ó ń wàásù pé kí àwọn èèyàn ṣèrìbọmi láti fi hàn pé wọ́n ti ronú pìwà dà, kí wọ́n lè rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà.+
4 Jòhánù Onírìbọmi wà nínú aginjù, ó ń wàásù pé kí àwọn èèyàn ṣèrìbọmi láti fi hàn pé wọ́n ti ronú pìwà dà, kí wọ́n lè rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà.+