-
Àìsáyà 51:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ẹ gbé ojú yín sókè sí ọ̀run,
Kí ẹ sì wo ayé nísàlẹ̀.
Torí pé ọ̀run máa fẹ́ lọ bí èéfín;
Ayé máa gbó bí aṣọ,
Àwọn tó ń gbé ibẹ̀ sì máa kú bíi kòkòrò abìyẹ́ tó ń mùjẹ̀.
-