Jóṣúà 23:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Ẹ wò ó! Mi ò ní pẹ́ kú,* ẹ sì mọ̀ dáadáa pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín àti gbogbo ara* yín pé kò sí ìkankan nínú gbogbo ìlérí tó dáa tí Jèhófà Ọlọ́run yín ṣe fún yín tí kò ṣẹ. Gbogbo wọn ló ṣẹ fún yín. Ìkankan nínú wọn ò kùnà.+ Àìsáyà 40:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Koríko tútù máa ń gbẹ dà nù,Ìtànná máa ń rọ,Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wa máa wà títí láé.”+ Mátíù 24:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ọ̀run àti ayé máa kọjá lọ, àmọ́ ó dájú pé àwọn ọ̀rọ̀ mi ò ní kọjá lọ.+
14 “Ẹ wò ó! Mi ò ní pẹ́ kú,* ẹ sì mọ̀ dáadáa pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín àti gbogbo ara* yín pé kò sí ìkankan nínú gbogbo ìlérí tó dáa tí Jèhófà Ọlọ́run yín ṣe fún yín tí kò ṣẹ. Gbogbo wọn ló ṣẹ fún yín. Ìkankan nínú wọn ò kùnà.+