Mátíù 26:57 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Àwọn tó mú Jésù wá mú un lọ sọ́dọ̀ Káyáfà+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà, níbi tí àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn àgbààgbà kóra jọ sí.+ Lúùkù 22:54, 55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 54 Wọ́n wá fàṣẹ ọba mú un, wọ́n sì mú un lọ,+ wọ́n mú un wá sínú ilé àlùfáà àgbà; àmọ́ Pétérù ń tẹ̀ lé wọn ní òkèèrè.+ 55 Nígbà tí wọ́n dáná láàárín àgbàlá, tí wọ́n sì jọ jókòó, Pétérù jókòó láàárín wọn.+
57 Àwọn tó mú Jésù wá mú un lọ sọ́dọ̀ Káyáfà+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà, níbi tí àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn àgbààgbà kóra jọ sí.+
54 Wọ́n wá fàṣẹ ọba mú un, wọ́n sì mú un lọ,+ wọ́n mú un wá sínú ilé àlùfáà àgbà; àmọ́ Pétérù ń tẹ̀ lé wọn ní òkèèrè.+ 55 Nígbà tí wọ́n dáná láàárín àgbàlá, tí wọ́n sì jọ jókòó, Pétérù jókòó láàárín wọn.+