-
Mátíù 26:65, 66Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
65 Àlùfáà àgbà fa aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀ ya, ó ní: “Ó ti sọ̀rọ̀ òdì! Kí la tún fẹ́ fi àwọn ẹlẹ́rìí ṣe? Ẹ wò ó! Ẹ ti gbọ́ ọ̀rọ̀ òdì náà. 66 Kí lèrò yín?” Wọ́n fèsì pé: “Ikú ló tọ́ sí i.”+
-