Mátíù 21:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Nígbà tí wọ́n rí ọmọ náà, àwọn tó ń dáko náà sọ fún ara wọn pé, ‘Ẹni tó máa jogún rẹ̀ nìyí.+ Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká pa á, ká sì gba ogún rẹ̀!’
38 Nígbà tí wọ́n rí ọmọ náà, àwọn tó ń dáko náà sọ fún ara wọn pé, ‘Ẹni tó máa jogún rẹ̀ nìyí.+ Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká pa á, ká sì gba ogún rẹ̀!’