Jòhánù 19:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 wọ́n ń wá sọ́dọ̀ rẹ̀ ṣáá, wọ́n sì ń sọ pé: “A kí ọ o,* ìwọ Ọba Àwọn Júù!” Wọ́n sì ń gbá a létí léraléra.+
3 wọ́n ń wá sọ́dọ̀ rẹ̀ ṣáá, wọ́n sì ń sọ pé: “A kí ọ o,* ìwọ Ọba Àwọn Júù!” Wọ́n sì ń gbá a létí léraléra.+