Lúùkù 23:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Àwọn èèyàn sì dúró, wọ́n ń wòran. Àmọ́ àwọn alákòóso ń yínmú, wọ́n ń sọ pé: “Ó gba àwọn ẹlòmíì là; kó gba ara rẹ̀ là tó bá jẹ́ òun ni Kristi ti Ọlọ́run, Àyànfẹ́.”+
35 Àwọn èèyàn sì dúró, wọ́n ń wòran. Àmọ́ àwọn alákòóso ń yínmú, wọ́n ń sọ pé: “Ó gba àwọn ẹlòmíì là; kó gba ara rẹ̀ là tó bá jẹ́ òun ni Kristi ti Ọlọ́run, Àyànfẹ́.”+