Mátíù 27:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Láti wákàtí kẹfà* lọ, òkùnkùn ṣú bo gbogbo ilẹ̀ náà, títí di wákàtí kẹsàn-án.*+ Lúùkù 23:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Ó ti tó nǹkan bíi wákàtí kẹfà* báyìí, síbẹ̀ òkùnkùn ṣú bo gbogbo ilẹ̀ náà títí di wákàtí kẹsàn-án,*+
44 Ó ti tó nǹkan bíi wákàtí kẹfà* báyìí, síbẹ̀ òkùnkùn ṣú bo gbogbo ilẹ̀ náà títí di wákàtí kẹsàn-án,*+