Mátíù 28:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àmọ́ áńgẹ́lì náà sọ fún àwọn obìnrin náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù, torí mo mọ̀ pé Jésù tí wọ́n kàn mọ́gi lẹ̀ ń wá.+ 6 Kò sí níbí, torí a ti jí i dìde, bó ṣe sọ gẹ́lẹ́.+ Ẹ wá wo ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí.
5 Àmọ́ áńgẹ́lì náà sọ fún àwọn obìnrin náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù, torí mo mọ̀ pé Jésù tí wọ́n kàn mọ́gi lẹ̀ ń wá.+ 6 Kò sí níbí, torí a ti jí i dìde, bó ṣe sọ gẹ́lẹ́.+ Ẹ wá wo ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí.