-
Mátíù 13:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Lọ́jọ́ yẹn, Jésù kúrò nínú ilé, ó sì jókòó sétí òkun. 2 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn kóra jọ sọ́dọ̀ rẹ̀ débi pé ó wọ ọkọ̀ ojú omi, ó jókòó, gbogbo àwọn èrò náà sì dúró sí etíkun.+
-
-
Lúùkù 8:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Nígbà tí èrò rẹpẹtẹ ti kóra jọ pẹ̀lú àwọn tó ń lọ bá a láti ìlú dé ìlú, ó fi àpèjúwe kan sọ̀rọ̀,+ ó ní:
-