Jòhánù 20:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ó dájú pé Jésù tún ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì míì níṣojú àwọn ọmọ ẹ̀yìn, tí a ò kọ sínú àkájọ ìwé yìí.+ 31 Àmọ́ a kọ àwọn yìí sílẹ̀ kí ẹ lè gbà gbọ́ pé Jésù ni Kristi, Ọmọ Ọlọ́run, kí ẹ sì lè ní ìyè nípasẹ̀ orúkọ rẹ̀ tí ẹ bá gbà gbọ́.+
30 Ó dájú pé Jésù tún ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì míì níṣojú àwọn ọmọ ẹ̀yìn, tí a ò kọ sínú àkájọ ìwé yìí.+ 31 Àmọ́ a kọ àwọn yìí sílẹ̀ kí ẹ lè gbà gbọ́ pé Jésù ni Kristi, Ọmọ Ọlọ́run, kí ẹ sì lè ní ìyè nípasẹ̀ orúkọ rẹ̀ tí ẹ bá gbà gbọ́.+