Mátíù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Lẹ́yìn tí Jésù ṣèrìbọmi, ó jáde látinú omi lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀; sì wò ó! ọ̀run ṣí sílẹ̀,+ ó sì rí i tí ẹ̀mí Ọlọ́run ń sọ̀ kalẹ̀ bí àdàbà bọ̀ wá sórí rẹ̀.+ Máàkù 1:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nígbà yẹn, Jésù wá láti Násárẹ́tì ti Gálílì, Jòhánù sì ṣèrìbọmi fún un ní Jọ́dánì.+ 10 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, bó ṣe ń jáde látinú omi, ó rí i tí ọ̀run ń pínyà, ẹ̀mí sì ń bọ̀ wá sórí rẹ̀ bí àdàbà.+
16 Lẹ́yìn tí Jésù ṣèrìbọmi, ó jáde látinú omi lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀; sì wò ó! ọ̀run ṣí sílẹ̀,+ ó sì rí i tí ẹ̀mí Ọlọ́run ń sọ̀ kalẹ̀ bí àdàbà bọ̀ wá sórí rẹ̀.+
9 Nígbà yẹn, Jésù wá láti Násárẹ́tì ti Gálílì, Jòhánù sì ṣèrìbọmi fún un ní Jọ́dánì.+ 10 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, bó ṣe ń jáde látinú omi, ó rí i tí ọ̀run ń pínyà, ẹ̀mí sì ń bọ̀ wá sórí rẹ̀ bí àdàbà.+