-
Jẹ́nẹ́sísì 5:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Kénánù pé ẹni àádọ́rin (70) ọdún, ó wá bí Máhálálélì.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 5:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Lẹ́yìn tó bí Járédì, Máhálálélì tún lo ọgọ́rùn-ún mẹ́jọ ó lé ọgbọ̀n (830) ọdún. Ó sì bí àwọn ọmọ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.
-