Mátíù 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Èṣù wá fi í sílẹ̀,+ sì wò ó! àwọn áńgẹ́lì wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ìránṣẹ́ fún un.+ Hébérù 4:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Torí àlùfáà àgbà tí a ní kì í ṣe ẹni tí kò lè bá wa kẹ́dùn fún àwọn àìlera wa,+ àmọ́ ó jẹ́ ẹni tí a ti dán wò ní gbogbo ọ̀nà bíi tiwa, àmọ́ tí kò ní ẹ̀ṣẹ̀.+
15 Torí àlùfáà àgbà tí a ní kì í ṣe ẹni tí kò lè bá wa kẹ́dùn fún àwọn àìlera wa,+ àmọ́ ó jẹ́ ẹni tí a ti dán wò ní gbogbo ọ̀nà bíi tiwa, àmọ́ tí kò ní ẹ̀ṣẹ̀.+