Mátíù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bákan náà, lẹ́yìn tó kúrò ní Násárẹ́tì, ó wá lọ ń gbé ní Kápánáúmù + lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkun ní agbègbè Sébúlúnì àti Náfútálì,
13 Bákan náà, lẹ́yìn tó kúrò ní Násárẹ́tì, ó wá lọ ń gbé ní Kápánáúmù + lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkun ní agbègbè Sébúlúnì àti Náfútálì,