Mátíù 7:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbà tí Jésù sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí tán, ohun tó ṣẹlẹ̀ ni pé bó ṣe ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ ya àwọn èrò náà lẹ́nu,+ Jòhánù 7:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Àwọn òṣìṣẹ́ náà fèsì pé: “Èèyàn kankan ò sọ̀rọ̀ báyìí rí.”+
28 Nígbà tí Jésù sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí tán, ohun tó ṣẹlẹ̀ ni pé bó ṣe ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ ya àwọn èrò náà lẹ́nu,+