ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 4:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, wọ́n pa àwọ̀n wọn tì, wọ́n sì tẹ̀ lé e.+

  • Mátíù 6:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 “Torí náà, ẹ máa wá Ìjọba náà àti òdodo Rẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, gbogbo nǹkan mìíràn yìí la sì máa fi kún un fún yín.+

  • Mátíù 19:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ni Pétérù bá fèsì pé: “Wò ó! A ti fi ohun gbogbo sílẹ̀, a sì tẹ̀ lé ọ; kí ló máa wá jẹ́ tiwa?”+

  • Máàkù 1:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 ó sì pè wọ́n lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀. Torí náà, wọ́n fi Sébédè bàbá wọn sílẹ̀ sínú ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú àwọn alágbàṣe, wọ́n sì tẹ̀ lé e.

  • Lúùkù 18:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Àmọ́ Pétérù sọ pé: “Wò ó! A ti fi àwọn nǹkan tí a ní sílẹ̀, a sì ti tẹ̀ lé ọ.”+

  • Fílípì 3:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Yàtọ̀ síyẹn, mo ti ka ohun gbogbo sí àdánù nítorí ìmọ̀ nípa Kristi Jésù Olúwa mi ṣeyebíye ju ohun gbogbo lọ. Nítorí rẹ̀, mo ti gbé ohun gbogbo sọ nù, mo sì kà wọ́n sí ọ̀pọ̀ pàǹtírí,* kí n lè jèrè Kristi,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́