Mátíù 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, ó na ọwọ́ rẹ̀, ó sì fọwọ́ kàn án, ó ní: “Mo fẹ́ bẹ́ẹ̀! Kí o mọ́.”+ Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, a wẹ ẹ̀tẹ̀ rẹ̀ mọ́.+ Máàkù 1:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Àánú rẹ̀ wá ṣe é, ó na ọwọ́ rẹ̀, ó sì fọwọ́ kàn án, ó wá sọ fún un pé: “Mo fẹ́ bẹ́ẹ̀! Kí o mọ́.”+
3 Torí náà, ó na ọwọ́ rẹ̀, ó sì fọwọ́ kàn án, ó ní: “Mo fẹ́ bẹ́ẹ̀! Kí o mọ́.”+ Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, a wẹ ẹ̀tẹ̀ rẹ̀ mọ́.+