9 Lẹ́yìn ìyẹn, bí Jésù ṣe ń kúrò níbẹ̀, ó tajú kán rí ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Mátíù, tó jókòó sí ọ́fíìsì àwọn agbowó orí, ó sì sọ fún un pé: “Máa tẹ̀ lé mi.” Ló bá dìde, ó sì tẹ̀ lé e.+
14 Bó ṣe ń kọjá lọ, ó tajú kán rí Léfì ọmọ Áfíọ́sì tó jókòó sí ọ́fíìsì àwọn agbowó orí, ó sì sọ fún un pé: “Máa tẹ̀ lé mi.” Ló bá dìde, ó sì tẹ̀ lé e.+