Mátíù 9:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, ẹ lọ kọ́ ohun tí ọ̀rọ̀ yìí túmọ̀ sí: ‘Àánú ni mo fẹ́, kì í ṣe ẹbọ.’+ Torí kì í ṣe àwọn olódodo ni mo wá pè, àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni.” 1 Tímótì 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọ̀rọ̀ yìí ṣeé gbára lé, ó sì yẹ ká gbà á délẹ̀délẹ̀, pé: Kristi Jésù wá sí ayé láti gba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ là.+ Èmi sì ni ẹni àkọ́kọ́ lára wọn.+
13 Torí náà, ẹ lọ kọ́ ohun tí ọ̀rọ̀ yìí túmọ̀ sí: ‘Àánú ni mo fẹ́, kì í ṣe ẹbọ.’+ Torí kì í ṣe àwọn olódodo ni mo wá pè, àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni.”
15 Ọ̀rọ̀ yìí ṣeé gbára lé, ó sì yẹ ká gbà á délẹ̀délẹ̀, pé: Kristi Jésù wá sí ayé láti gba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ là.+ Èmi sì ni ẹni àkọ́kọ́ lára wọn.+