Mátíù 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ tí o bá ń gbàdúrà, lọ sínú yàrá àdáni rẹ, lẹ́yìn tí o bá ti ilẹ̀kùn rẹ, gbàdúrà sí Baba rẹ tó wà ní ìkọ̀kọ̀.+ Baba rẹ tó ń rí ohun tó wà ní ìkọ̀kọ̀ sì máa san ọ́ lẹ́san. Máàkù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó gun òkè kan, ó pe àwọn tó fẹ́ yàn,+ wọ́n sì wá bá a.+
6 Àmọ́ tí o bá ń gbàdúrà, lọ sínú yàrá àdáni rẹ, lẹ́yìn tí o bá ti ilẹ̀kùn rẹ, gbàdúrà sí Baba rẹ tó wà ní ìkọ̀kọ̀.+ Baba rẹ tó ń rí ohun tó wà ní ìkọ̀kọ̀ sì máa san ọ́ lẹ́san.