Mátíù 5:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Aláyọ̀ ni àwọn tí wọ́n ṣe inúnibíni sí nítorí òdodo,+ torí Ìjọba ọ̀run jẹ́ tiwọn. 11 “Aláyọ̀ ni yín tí àwọn èèyàn bá pẹ̀gàn yín,+ tí wọ́n ṣe inúnibíni sí yín,+ tí wọ́n sì parọ́ oríṣiríṣi ohun burúkú mọ́ yín nítorí mi.+ Jòhánù 17:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo ti sọ ọ̀rọ̀ rẹ fún wọn, àmọ́ ayé ti kórìíra wọn, torí wọn kì í ṣe apá kan ayé,+ bí èmi ò ṣe jẹ́ apá kan ayé. 1 Pétérù 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Síbẹ̀, tí ẹ bá tiẹ̀ jìyà nítorí òdodo, inú yín máa dùn.+ Àmọ́ ẹ má bẹ̀rù ohun tí wọ́n ń bẹ̀rù,* ẹ má sì jáyà.+
10 “Aláyọ̀ ni àwọn tí wọ́n ṣe inúnibíni sí nítorí òdodo,+ torí Ìjọba ọ̀run jẹ́ tiwọn. 11 “Aláyọ̀ ni yín tí àwọn èèyàn bá pẹ̀gàn yín,+ tí wọ́n ṣe inúnibíni sí yín,+ tí wọ́n sì parọ́ oríṣiríṣi ohun burúkú mọ́ yín nítorí mi.+
14 Mo ti sọ ọ̀rọ̀ rẹ fún wọn, àmọ́ ayé ti kórìíra wọn, torí wọn kì í ṣe apá kan ayé,+ bí èmi ò ṣe jẹ́ apá kan ayé.
14 Síbẹ̀, tí ẹ bá tiẹ̀ jìyà nítorí òdodo, inú yín máa dùn.+ Àmọ́ ẹ má bẹ̀rù ohun tí wọ́n ń bẹ̀rù,* ẹ má sì jáyà.+