-
Mátíù 8:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Nígbà tó wọ Kápánáúmù, ọ̀gágun kan wá bá a, ó ń bẹ̀ ẹ́,+ 6 ó sì ń sọ pé: “Ọ̀gá, àrùn rọpárọsẹ̀ dá ìránṣẹ́ mi dùbúlẹ̀ sínú ilé, ìyà sì ń jẹ ẹ́ gidigidi.”
-