Mátíù 9:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! wọ́n ń gbé ọkùnrin kan bọ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó ní àrùn rọpárọsẹ̀, ó sì dùbúlẹ̀ sórí ibùsùn. Nígbà tó rí ìgbàgbọ́ tí wọ́n ní, Jésù sọ fún alárùn rọpárọsẹ̀ náà pé: “Mọ́kàn le, ọmọ! A dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́.”+ Máàkù 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tí Jésù rí ìgbàgbọ́ tí wọ́n ní,+ ó sọ fún alárùn rọpárọsẹ̀ náà pé: “Ọmọ, a dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́.”+
2 Wò ó! wọ́n ń gbé ọkùnrin kan bọ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó ní àrùn rọpárọsẹ̀, ó sì dùbúlẹ̀ sórí ibùsùn. Nígbà tó rí ìgbàgbọ́ tí wọ́n ní, Jésù sọ fún alárùn rọpárọsẹ̀ náà pé: “Mọ́kàn le, ọmọ! A dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́.”+
5 Nígbà tí Jésù rí ìgbàgbọ́ tí wọ́n ní,+ ó sọ fún alárùn rọpárọsẹ̀ náà pé: “Ọmọ, a dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́.”+