Lúùkù 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àwọn ti orí àpáta ni àwọn tó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, wọ́n fi ayọ̀ tẹ́wọ́ gbà á, àmọ́ àwọn yìí kò ní gbòǹgbò. Wọ́n gbà gbọ́ fúngbà díẹ̀, àmọ́ ní àsìkò ìdánwò, wọ́n yẹsẹ̀.+
13 Àwọn ti orí àpáta ni àwọn tó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, wọ́n fi ayọ̀ tẹ́wọ́ gbà á, àmọ́ àwọn yìí kò ní gbòǹgbò. Wọ́n gbà gbọ́ fúngbà díẹ̀, àmọ́ ní àsìkò ìdánwò, wọ́n yẹsẹ̀.+