-
Mátíù 14:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Àwọn tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi náà wá tẹrí ba* fún un, wọ́n sọ pé: “Ọmọ Ọlọ́run ni ọ́ lóòótọ́.”
-
-
Jòhánù 20:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Àmọ́ a kọ àwọn yìí sílẹ̀ kí ẹ lè gbà gbọ́ pé Jésù ni Kristi, Ọmọ Ọlọ́run, kí ẹ sì lè ní ìyè nípasẹ̀ orúkọ rẹ̀ tí ẹ bá gbà gbọ́.+
-