Máàkù 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn tí Jésù tún fi ọkọ̀ ojú omi sọdá sí èbúté tó wà ní òdìkejì, èrò rẹpẹtẹ kóra jọ sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì wà létí òkun.+
21 Lẹ́yìn tí Jésù tún fi ọkọ̀ ojú omi sọdá sí èbúté tó wà ní òdìkejì, èrò rẹpẹtẹ kóra jọ sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì wà létí òkun.+