Lúùkù 5:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Lọ́jọ́ kan, bó ṣe ń kọ́ni, àwọn Farisí àti àwọn olùkọ́ Òfin tí wọ́n wá láti gbogbo abúlé Gálílì àti Jùdíà àti Jerúsálẹ́mù jókòó níbẹ̀; agbára Jèhófà* sì wà lára rẹ̀ láti wo àwọn èèyàn sàn.+
17 Lọ́jọ́ kan, bó ṣe ń kọ́ni, àwọn Farisí àti àwọn olùkọ́ Òfin tí wọ́n wá láti gbogbo abúlé Gálílì àti Jùdíà àti Jerúsálẹ́mù jókòó níbẹ̀; agbára Jèhófà* sì wà lára rẹ̀ láti wo àwọn èèyàn sàn.+